Èní yí je ojúmó ire. Ifíhan Awón Àwòrán Orí Oko sí n tè síwájú ní kíkún .
Akosílè yìí je ònà làti se ifíhan awón eso at eere orí oko wa tí áyà pèlú ohun áyàwòràn ero ìbánìsòrò waa.
Àwòrán eso tá a fé se afíhàn rè léní ni eso cashew tuntun orí oko wa.
Mo ya àwòrán yìí pèlú Ohun aya àwòrán èro ìbánisòrò Blackberry Q10 .
Omo iya mi