Ko si eni too le ba Kristi pade lai mo. Okan to a to soji yio si to yipada yio no yio si ma fi awon ami re han. Enikeni to igbala re ko da a loju ko to i di atunbi. Ojulowo isoji no ibasepo pelu ojulowo iyipada Latin inu iku si iye. 1Johannu 3:8-9; 2 Kor.5:17.
Ayederu iyipada okan to gbode kan bayi. Idi niyi to opolopo a won to o pe wra won no kristieni fi nmu iwosi ba ijo nipase igbeaye to ko we dede, to won si npada sinu ice aye ati ese. Nje iyipada okan re he ojulowo bi? Oni Lati ni idalebi okan to o daju ti o si jinle nipa ese. Eyi ko daju ninu opolopo ijo lode oni. Nibiti ese tooto ba was, a ko nilo lati ma to, fa tabi tenumo o pelu agbara eran ara. A won elese yio jowo ara won fun Kristi lai fi ipa mu won. Bi won ko ba we bee, iyipada okan ti o jinle ko ni je ki won o jeun tabi sun titi won o fi jowo ara won. Acts2:37; 16:30.
Congratulations @holuwa! You have completed some achievement on Steemit and have been rewarded with new badge(s) :
Award for the number of upvotes received
You published 4 posts in one day
Click on any badge to view your own Board of Honor on SteemitBoard.
To support your work, I also upvoted your post!
For more information about SteemitBoard, click here
If you no longer want to receive notifications, reply to this comment with the word
STOP